Gbogbo ènìyàn ni a bí ní òmìnira; iyì àti è̩tó̩ kò̩ò̩kan sì dó̩gba. Wó̩n ní è̩bùn ti làákàyè àti ti è̩rí‐o̩kàn, ó sì ye̩ kí wo̩n ó máa hùwà sí ara wo̩n gé̩gé̩ bí o̩mo̩ ìyá.
